Search This Blog

Monday, June 2, 2008

USE OF HONEY IN YORUBA LANGUAGE



http://www.konga.com?k_id=HIWORKS
BI ASE LE LO OYIN IGAN

Oyin Igan je okan lara ohun ti Olorun da fun lilo wa sugbon opo wa ko mo bi ase le lo Idi niyi ti ile ise toun lo ewe ati egbo fi so die lara ona ti a le gba lo Oyin Igan.


1 OGUN OJU ; Ti Oju re ban se pin, tabi ti o nyun o, ti o pon . Po Oyin ati alubosa funfun pomon ara won. Maa kan si oju mejeji.

2. INU RIRUN; Lo Ewuro po mo Oyin ma lo sibi meji lehin onje ale.
3. EGBO; Ewuro po mon Oyin ma fi si oju egbo na.
4. EYIN OMODE; Oyin Igan ati Omi Osan wewe mon ara won. Ki o si fun Omo na ni sibi kan lemeji lojumo lehin onje.
5. IKO IFE (TUBERCULUS); Lo Atare, Ayu, Iyo ati Orogbo pelu O yin Igan sinu Igo. Agba sibi meji ni igba meta lojumo
6. AIRI ORUN SUN; Maa mu Oyin Igan sun. Sibi meji lalale.
7. AILERA NINU OSU OBINRIN; Nkan osu to nse segesege tabi to dudu (STOMACHPAIN) Lo sibi Oyin Merinmerin ni Emerin lojumo.
8 ARONMOLEGUN; Lo Ewuro po mo oyin Igan fi pa ibi ti on ro E. Ki o lo sibi meji li ojojumo ni owuro kutukutu.
9AKANDUN TABI EEWO(BOIL). Lo Ewa ati Kaun po mo Oyin Igan. Ma fira ibe.
10. OGBE INU(ULCER); Maa mu sibi Oyin meta ni owuro kutukutu ni wakati kan ki o to jeun aaro.
11. FUN ATO KIKI(SEMEN BOOST); Po eyin tutu po mo Oyin sibi Maarun Lo gbogbo re leekan naa.
12. IKO EGBE; Po Omi Igbin ati Oyin po mo ara won .Sibi nla meta leemeta lojojumo. Omode sibi kan laaro ati lale.
13. JEDIJEDI; Lo efirin, Omi Osanwewe po mo Oyin Igan . sibi meta laro ati lale. Lojojumon.
14. ARUN ETI; Ti eti ban se oyun tabi ti o nrin eniyan, fi omi gbigbona po iyo die ati oyin mo ara won ma kan si eti mejeji laro ati lale.
15. KOKORO ENU; Po Oyin Igan po mo Osan wewe fifo enu ni igba meta lojojumo.
16. ILE GBIGBONA; Lo ewuro po mo Oyin Igan fi pa gbogbo ara sibi mejimeji, lemeta lojumo.
17. INU DIDUN LEHIN TO BINRIN BA BIMO; Obinrin naa yio malo oyin sibi mejimeji lemeta lojumo.
18. OMO TI O NTO SILE; Ki o maa mu sibi Oyin Igan mejimeji sun titi tiko fi ni to sile mo.
19. IKO; Lo orogbo ki o daa sinu Oyin Igan lehin nab ere si laa tabi ki o maa loo sibi kan kan ni wakati metameta. Omode sibi kekere.
20. Maafi Oyin Igan mu Ogi tabi Tea. O dara.
21.OGUN OJUPIPON; Ma kan oyin si lemeta loojumo.
22. ARUNSU; Lo ewe ejirin po mo oyin igan sibi merin lemeta lojumo.
23 .ATOGBE; Omi ewe ewuro po mo Oyin Igan sibi merin lemeta lojumo.
24. ROPAROSE; Fi ito re lo Oyin Igan lale.
25. EJE RIRUN; Lo ayu po mo Oyin Igan sibi meta lojumo laro ati lale.
26. OKO LILE; Ma fi ogede dudu sise kan oyin je.
27. OGUN EJE; Lo omunu ewuro po mo Oyin Igan sibi meta loojo,.
28. INU RIRUN; Po iyo mo Oyin Igan sibi meta lojumo.
29. FUN ARA DIDAN; Po Oyin Igan mo adiagbon ma fi pa ara.
30. FUN IFA RUN AGBON.;Po etu mo oyin igan ma fi pa.
31.FUN KOKORO; Lo eru awon ka imi ojo etu po mo oyin igan mafi pa ara.
32. FUN ARAN; Omi osan wewe po mo oyin igan sibi meta meta lojumo.
33.KI INU OBIRIN GBONA. Lo ayu po mo oyin igan sibi merin lemeta lojumo.
34FUN IBA REFUNREFUN;Lo ayu po mo omi osan wewe eyin ati oyin igan sibi merin ni igba meta lojumo.
35. BI INA BA JO ENIYAN; Ma fi oyin pa ni gbogbo igba.
36 BI OMI GBIGBONA BA DAJO ENIYAN. Ma fi oyin igan pa.
37. ALEFO LARA OMODE; Lo eru awon ka etui mi ojo po mo Oyin Igan ma fi pa ni gbogbo igba (mase te fo rara).
38. OGUN EJE; Omi csan wewe eyin tutu mo oyin igan sibi merin ni igba meta lojumo.
39. BI ARA BAUN GBONA:- Omi ewuro ti agbo la ifi omi si ale fi iyo gbo a po mon Oyin Igan sibi meji lee meta loju mo fi pa gbogbo ara.
40. BI INU BA DUN OBIRIN; Lo ayu po mo Oyin Igan sibi meta lee meta lojumo .
41.OGUN ARUNSU; Fi iyo gbo efirin po mo oyin igan sibi meta lee meta lojumo.
42.NKAN OSU OBIRIN TO UN SE SEGESEGE; Lo ayu po mo omi osan wewe ati oyin igan .sibi meta lee meta lojumo.
43. OGUN ATOSI. Omi jaganyin ;kun die, ayu po mo Oyin Igan .sibi merin lee meta lojumo.
44.KI ENI TO BA NI ATOGBE ;Ma fi Oyin Igan mu Ogi ati Tea. ma din sugar ku lara.
45.Ki eni to ba tile ni OGOJI ODUN Ma fi OYIN IGAN mu Ogi tabi Tea.
46. OGUN DIDIN ISANRA KU; Ki o fi omi se Haha agbado ki o ma fi Oyin Igan mu bi Tea laro ati lale.
47. KI AGBALAGBA Ma lo Oyin Igan lati mu Tea tabi Ogi O ma un je ki Opolo ji pepe.
48.FUN OKUN. AGBARA OPOLO JI PEPE. Ma fi Oyin Igan mu (Oda Herbal Tea) ni gbogbo igba ile ise egbo gi ni ati ise.
49.FUN EJE RIRU ; Ki e ma fi Oyin Igan mu Oda Herbal Tea..

CALL or SMS +2347042900201
or Email
csaproductivity@gmail.com for Your further Enquiry.

4 comments:

Unknown said...

I really like your blogger, kindly make more update, people in america would contact you soon. Stay blessed.
Peter

Unknown said...

Ogun Iban Todaju
Ao mun ewe eyin Olobe ati eyin re , Ao lo mo eyo atare. Ao wa fi sin gbere kan si arin ori wa.

Unknown said...

When i read ur profile, i realised u are an engineer, yet resourceful in local medication. this very good. welldone

Unknown said...

ojogbon eku ise iwadi-ijinle,nbani kiebawa te awon alaye nipa lilo oyin-igan yi sita fun anfani gbogbo eda ti yio si wulo lopolopo